Back to Top

Afeezee - Atidé Lyrics



Afeezee - Atidé Lyrics
Official




Ati dé ati dé
Ati dé ati dé
Ọmọdé ọmọdé
Sọ f'álagbá
P'atidé

Ati dé ati dé
Ati dé ati dé
It's our time
Atidé
Atidé atidé


Irọ́ tó lọ f'ógún ọdún
Olè t'ójà lọ́gànjọ́ òru
Olówó tó sùn tita jí
Gbogbo yín lẹ́ma jẹ́jọ́ ẹ̀san

Irọ́ tó lọ f'ógún ọdún
Olè t'ójà lọ́gànjọ́ òru
Olówó tó sùn tita jí
Gbogbo yín lẹ́ma jẹ́jọ́ ẹ̀san


Ẹnáwọ́ sókè yes yes

Ẹsọ̀rọ̀ sókè yes yes

Òmìnira wa yes yes

Òní lama gbà yes yes


Ẹnáwọ́ sókè yes yes

Ẹsọ̀rọ̀ sókè yes yes

Òmìnira wa yes yes

Òní lama gbà yes yes


Ati dé ati dé
Ati dé ati dé
Ọmọdé ọmọdé
Sọ f'álagbá
P'atidé

Ati dé ati dé
Ati dé ati dé
It's our time
Atidé
Atidé atidé


Ẹyín tẹ f'ayé jẹ wá
Ẹyín tẹ f'ebi pawá
Etún fẹ́ wá gbagbára
Awá òní gbà nílù wá

Ẹyín tẹ f'ayé jẹ wá
Ẹyín tẹ f'ebi pawá
Etún fẹ́ wá gbagbára
Awá òní gbà nílù wá


Ẹnáwọ́ sókè yes yes

Ẹsọ̀rọ̀ sókè yes yes

Òmìnira wa yes yes

Òní lama gbà yes yes


Ẹnáwọ́ sókè yes yes

Ẹsọ̀rọ̀ sókè yes yes

Òmìnira wa yes yes

Òní lama gbà yes yes

Ati dé ati dé
Ati dé ati dé
Ọmọdé ọmọdé
Sọ f'álagbá
P'atidé

Ati dé ati dé
Ati dé ati dé
It's our time
Atidé
Atidé atidé

Ẹnáwọ́ sókè yes yes

Ẹsọ̀rọ̀ sókè yes yes

Òmìnira wa yes yes

Òní lama gbà yes yes


Ẹnáwọ́ sókè yes yes

Ẹsọ̀rọ̀ sókè yes yes

Òmìnira wa yes yes

Òní lama gbà yes yes
[ Correct these Lyrics ]

[ Correct these Lyrics ]

We currently do not have these lyrics. If you would like to submit them, please use the form below.


We currently do not have these lyrics. If you would like to submit them, please use the form below.


English

Ati dé ati dé
Ati dé ati dé
Ọmọdé ọmọdé
Sọ f'álagbá
P'atidé

Ati dé ati dé
Ati dé ati dé
It's our time
Atidé
Atidé atidé


Irọ́ tó lọ f'ógún ọdún
Olè t'ójà lọ́gànjọ́ òru
Olówó tó sùn tita jí
Gbogbo yín lẹ́ma jẹ́jọ́ ẹ̀san

Irọ́ tó lọ f'ógún ọdún
Olè t'ójà lọ́gànjọ́ òru
Olówó tó sùn tita jí
Gbogbo yín lẹ́ma jẹ́jọ́ ẹ̀san


Ẹnáwọ́ sókè yes yes

Ẹsọ̀rọ̀ sókè yes yes

Òmìnira wa yes yes

Òní lama gbà yes yes


Ẹnáwọ́ sókè yes yes

Ẹsọ̀rọ̀ sókè yes yes

Òmìnira wa yes yes

Òní lama gbà yes yes


Ati dé ati dé
Ati dé ati dé
Ọmọdé ọmọdé
Sọ f'álagbá
P'atidé

Ati dé ati dé
Ati dé ati dé
It's our time
Atidé
Atidé atidé


Ẹyín tẹ f'ayé jẹ wá
Ẹyín tẹ f'ebi pawá
Etún fẹ́ wá gbagbára
Awá òní gbà nílù wá

Ẹyín tẹ f'ayé jẹ wá
Ẹyín tẹ f'ebi pawá
Etún fẹ́ wá gbagbára
Awá òní gbà nílù wá


Ẹnáwọ́ sókè yes yes

Ẹsọ̀rọ̀ sókè yes yes

Òmìnira wa yes yes

Òní lama gbà yes yes


Ẹnáwọ́ sókè yes yes

Ẹsọ̀rọ̀ sókè yes yes

Òmìnira wa yes yes

Òní lama gbà yes yes

Ati dé ati dé
Ati dé ati dé
Ọmọdé ọmọdé
Sọ f'álagbá
P'atidé

Ati dé ati dé
Ati dé ati dé
It's our time
Atidé
Atidé atidé

Ẹnáwọ́ sókè yes yes

Ẹsọ̀rọ̀ sókè yes yes

Òmìnira wa yes yes

Òní lama gbà yes yes


Ẹnáwọ́ sókè yes yes

Ẹsọ̀rọ̀ sókè yes yes

Òmìnira wa yes yes

Òní lama gbà yes yes
[ Correct these Lyrics ]
Writer: Afeez Olagunju
Copyright: Lyrics © Afeezee

Back to: Afeezee



Afeezee - Atidé Video
(Show video at the top of the page)


Performed By: Afeezee
Language: English
Length: 2:30
Written by: Afeez Olagunju

Tags:
No tags yet