Back to Top

Afeezee - Thanksgiving Lyrics



Afeezee - Thanksgiving Lyrics
Official




Olúwa olúwa ẹsé
T'ẹ dójú tìmí
Olúwa olúwa ẹsé
T'ẹ dójú tìmí
Ọ̀tá pọ̀ nínú aiyé
Tán fẹ́ ko jú tìmí
Olúwa olúwa esé
T'ẹ dójú tìmí


Wọ́n sare sare
Láti bọ lájẹ́
Láti bọ lájẹ́

But olúwa mi dúró
Digbí o
Odúró digbí

Wọ́n wò mí sùn sùn
Pé kisúbú o
Wípé kisúbú

But olúwa mi dúró
Digbí o
Odúró digbí


Èmí á jó maa yọ̀
Ti n bá ronú oore tó se
Ẹ̀mí ájó maa yọ̀
Ti n bá ronú oore tó se
Óóre rẹ́ pọ́ pupọ̀
Nínú ilé àiyé mi
Èmí á jó maa yọ̀
Ti n bá ronú oore tó se


Jíá jó jíájó jíájó jíájó
Jíájó jíájó jíá dúpé o jíájó
Jíá jó jíájó jíájó jíájó
Jíájó jíájó mùkúlú mùkẹ jẹ́kájó


Baba mí momọ́pẹ́wá
Hmmm momọ́pẹ́wá
Baba mí momọ́pẹ́wá
Eh eh eh momọ́pẹ́wá

Melò n momakà nínú oore to se fún mi láyé mi
Melò n momakà nínú oore to se fún mi láyé mi


Ódé mi l'ádé
Ódé mi l'ọ́lá
Ófún mi láiyé
Ójẹ́ n ráyé gbé

Ódé mi l'ádé
Ódé mi l'ọ́lá
Ófún mi láiyé
Eh eh


Èmí á jó maa yọ̀
Ti n bá ronú oore tó se
Ẹ̀mí ájó maa yọ̀
Ti n bá ronú oore tó se
Óóre rẹ́ pọ́ pupọ̀
Nínú ilé àiyé mi
Èmí á jó maa yọ̀
Ti n bá ronú oore tó se


Jíá jó jíájó jíájó jíájó
Jíájó jíájó jíá dúpé o jíájó
Jíá jó jíájó jíájó jíájó
Jíájó jíájó mùkúlú mùkẹ jẹ́kájó

Jíá jó jíájó jíájó jíájó
Jíájó jíájó jíá dúpé o jíájó
Jíá jó jíájó jíájó jíájó
Jíájó jíájó mùkúlú mùkẹ jẹ́kájó.
[ Correct these Lyrics ]

[ Correct these Lyrics ]

We currently do not have these lyrics. If you would like to submit them, please use the form below.


We currently do not have these lyrics. If you would like to submit them, please use the form below.


English

Olúwa olúwa ẹsé
T'ẹ dójú tìmí
Olúwa olúwa ẹsé
T'ẹ dójú tìmí
Ọ̀tá pọ̀ nínú aiyé
Tán fẹ́ ko jú tìmí
Olúwa olúwa esé
T'ẹ dójú tìmí


Wọ́n sare sare
Láti bọ lájẹ́
Láti bọ lájẹ́

But olúwa mi dúró
Digbí o
Odúró digbí

Wọ́n wò mí sùn sùn
Pé kisúbú o
Wípé kisúbú

But olúwa mi dúró
Digbí o
Odúró digbí


Èmí á jó maa yọ̀
Ti n bá ronú oore tó se
Ẹ̀mí ájó maa yọ̀
Ti n bá ronú oore tó se
Óóre rẹ́ pọ́ pupọ̀
Nínú ilé àiyé mi
Èmí á jó maa yọ̀
Ti n bá ronú oore tó se


Jíá jó jíájó jíájó jíájó
Jíájó jíájó jíá dúpé o jíájó
Jíá jó jíájó jíájó jíájó
Jíájó jíájó mùkúlú mùkẹ jẹ́kájó


Baba mí momọ́pẹ́wá
Hmmm momọ́pẹ́wá
Baba mí momọ́pẹ́wá
Eh eh eh momọ́pẹ́wá

Melò n momakà nínú oore to se fún mi láyé mi
Melò n momakà nínú oore to se fún mi láyé mi


Ódé mi l'ádé
Ódé mi l'ọ́lá
Ófún mi láiyé
Ójẹ́ n ráyé gbé

Ódé mi l'ádé
Ódé mi l'ọ́lá
Ófún mi láiyé
Eh eh


Èmí á jó maa yọ̀
Ti n bá ronú oore tó se
Ẹ̀mí ájó maa yọ̀
Ti n bá ronú oore tó se
Óóre rẹ́ pọ́ pupọ̀
Nínú ilé àiyé mi
Èmí á jó maa yọ̀
Ti n bá ronú oore tó se


Jíá jó jíájó jíájó jíájó
Jíájó jíájó jíá dúpé o jíájó
Jíá jó jíájó jíájó jíájó
Jíájó jíájó mùkúlú mùkẹ jẹ́kájó

Jíá jó jíájó jíájó jíájó
Jíájó jíájó jíá dúpé o jíájó
Jíá jó jíájó jíájó jíájó
Jíájó jíájó mùkúlú mùkẹ jẹ́kájó.
[ Correct these Lyrics ]
Writer: Afeez Olagunju
Copyright: Lyrics © Afeezee

Back to: Afeezee



Afeezee - Thanksgiving Video
(Show video at the top of the page)


Performed By: Afeezee
Language: English
Length: 2:36
Written by: Afeez Olagunju

Tags:
No tags yet