Orun si
Orun si
Awon angeli lorun nkorin si baba
Orun si
Orun si
Awon angeli lorun nkorin si baba
Orun si
Orun si
Awon agba merin le logun nfori bale
Awon angeli won kun fayo
Won fun fere pelu duru
Won ke mimo mimo yi ite olorun ka
Won nkorin won filu won fogbo
Awon Angel kun Fayo lorun
Awon Angel kun Fayo lorun
Awon Angel kun Fayo lorun
Won nkorin pelu duru
Won nyin baba
Won fogo
Feni toni gbogbo ogo
Oke kekere fogo fun
Oke nla fiyin fun
At the mention of his name
Every knee shall bow
Every tongue confess
We sing awon angeli
Awon angeli kun fayo lorun
Awon angeli kun fayo lorun
Awon angeli kun fayo lorun
Awon angeli kun fayo lorun
Awon angeli kun fayo lorun
Awon angeli kun fayo lorun
Awon angeli kun fayo lorun
They are full of joy