Mo n rán e lo bayi. Mo mu e si okan mi
O le gan... o du n mi gan
Su gban mo n rán e lọ
Iwo ni kan ni mo fẹràn. Mo duro de e Su gban mo n je ko lọ
A pa de lana. O wa ni a la mi, o pade mi pelu ife ati omije lo ju re ni ro nu
Se o ni ife mi? Se O si fe je ki n lọ? Se O duro de mi
Ni gbagbogbo ni mo few a ni tosi
Jowo ma fi mi le. Mi o daju pe o rán ti mi
O mu gbogbo ife mi. O dara ti o ba rán ti mi
Bayi, mo lala idunu. Rán ibamuje mi kuro. Mu ayo mi wa
O fẹràn mi nitori o ri inu mi. Su gban mo fẹràn re si
Mo dabobo re. mi o ni je ko lọ
Iyebiye mi, ife mi. Jowo wi pe a wa lailai
Ki o gbe ke le mi mu ọwọ mi dani dada
Ma tu ọwọ wa mo