Everything that hurts will fade away
Strides when I am weak
Smiles when I can't see
Beyond my wounded state
It's not about me
We have not lived till we show love
Ìfé, bí eji òwúrò
L'átàgbàlá elédùmarè ló ti sè wá
Ìfé, tó tòrò míní míní
T'ábàwón ayé kan ò le bàjé
Jòwó féràn mi láì s'ètàn
Ònà ò jìn
Ojó ò pé
Ká tó lo
Ká tó lo
Ayé ò le
Ba se rí
Jòwó jó
Jòwó jó
Ìfé, bí eji òwúrò
L'átàgbàlá elédùmarè ló ti sè wá
Ìfé, tó tòrò míní míní
T'ábàwón ayé kan ò le bàjé
Jòwó féràn mi láì s'ètàn
We have not lived till we show love
We have not lived till we show love